27/01/2026
NJE SINIMA KOLEOSO YO PARÍ SI APA KẸ̀WÁ BÍ?
ÈYÍ NÍ ÀWỌN ÌDÍ TÍ A ṢE LÈ SỌPE KÒ LÈ PARÍ SÍBÈ
IYA ÀGBÀ ÌYẸN MAMA OSO GANGAN TO KÒ ILẸ̀ OSO SI KOLEOSO LEYIN. SO WÍPE IRAN OHUN KÒ LÈ PARUN. BÍ ERÉ YÍ BÁ TÁN SÍBÈ A JÉ WÍPE IRAN RẸ TÍ PARUN NÌYẸN
NÍNÚ APA KẸ̀WÁ LATI RI OSOPADE. ǸJẸ́ Ẹ̀JẸ̀ MOPE OSOPADE KÒ WÒ INU ÌWÉ PELU AWON TO KÚ. BEESINI IYA ÀGBÀ GAN KÒ WÒ INU ÌWÉ
TANI ỌMỌ TO GBE ÌWÉ OGUN OSO FAMILY YÍ. ÌWÉ AGBÁRA TÍ ÈNÌYÀN LÁSÁN KÒ LÈ FOWOKAN YATOSI EBI OSO. DÁJÚDÁJÚ LÁRA EBI OSO NÍ ỌMỌDÉBÌNRIN YẸN.
ỌMỌBÌNRIN TÍ KOLEOSO DE MỌ́LẸ̀ TO TÚN GBA IMOLE RẸ ÌYẸN NIPE Ọ FO OJÚ Ẹ. SE MOPE EEWON KOLEOSO SI WA LỌRUN ỌMỌBÌNRIN NA. Ó SÌ Ń BÁ SÚN. Ó SEESE KÍ ỌMỌBÌNRIN NA TIWA NÍNÚ OYUN BAYI FUN KOLEOSO
KINI ÌDÍ TÍ LALUDE FI LỌ SÍLÈ TO LỌ FARARAN WÍPE OHUN TÍ RÍ ẸNI TÍ OHUN YO FI ROPO NÍNÚ AFẸ́FẸ́. ǸJẸ́ Ẹ JÉ MOPE OSOPADE KÒ RÍ LALUDE PA
Ẹ KÚ OJÚ LỌ́NÀ KOLEOSO SEASON 3️⃣